News:

Happy World Ifa Festival !!

Main Menu

Oriki Ogun

Started by Omowale, Jan 26, 2023, 03:15 AM

Previous topic - Next topic

Omowale

From @Atipo :

Ògún bẹ́rí ọmọdé, ó ró ṣákeṣáke, ó bẹ́rí àgbà, ó ró gìdìgbì lálẹ̀, ijọ́ ni erú Ògún ti í bá mi a roko b'ẹ́lẹ́sìnrìn ṣàgbè
Ogun beheads the child, it lightly rolls, he beheads the elder, it rolls heavily, from that day I have become to fear Ogun, the one who clears weeds and helps the debter beg for money.

Ògún mọ́ mọ̀ jẹ́ mi rí ọ́ lúgbó òrìrí ẹ. Òrìrí rẹ ṣeji, Òrìrí rẹ ṣẹ́ta, ọni kó bá ti rórìrí yẹ ó yẹ kó ya ulé ẹlẹ́bọ
Ogun, may I not see you in the forest of your Oriri (I think oriri either refers to a food/animal ogun likes or perhaps a symbol of Ogun's presence), your oriri makes two, your Oriri comes in three, anyone who sees your oriri should quickly go offer a sacrifice.

@Atipo also shared with me this video, which we can hear an Ogun priestess recite Oriki Ogun: 
shrine of metals, a common offering to Ogun the orisha of war, hunting and technology:

~Manifest destiny from within~

Omowale


Bless @Iyanifa_Ifafunke_agbeke .

This is a short clip of Chief Adebayo Olasunkanmi Ifagbemisola (Akanji Onifa) reciting Oriki Ogun.~Manifest destiny from within~

Omowale

Ogun protect us.

Ogun mama je n ri soso
Ogun, does not let me see evil

Eni wa soso
don't let evil happen to me

Ase
a ri soso
Don't let me experience evil
~Manifest destiny from within~

Ayobamikale

Láti ọwọ́ Ayọ̀bámikalẹ́

Omowale

~Manifest destiny from within~