News:

Sùúrù ni baba ìwà.

Main Menu

Ori Prayer from Ogbekanran

Started by Omowale, Mar 16, 2023, 03:08 PM

Previous topic - Next topic

Omowale

Ogbèkànràn (Eji-Ogbe Okanran)

|| |
|| |
|| |
|  |

Ogbèkan Ọlọ̀kànràn kan
Adífá fún Orí
Orí wá ire lo ìlú Ìjẹ̀sà
Orí mi gbèmí, báun wá rere
Àkàrà ní ń wá rere fún epo

One ogbe, one Olokanran
Cast divination for Ori
Ori was seeking blessing in Ijesa town
Ori please support me, gather blessings for me
It is beans ball that seeks blessing for palm oil


16875710_fbimg16761566703276697_jpeg648e03c83aa930281fc3e4910407758d.jpeg
(Ori bibo)
~Manifest destiny from within~

Omowale

Àṣẹ Olódùmaré 🙏🏿
~Manifest destiny from within~