News:

Sùúrù ni baba ìwà.

Main Menu

Iwure Obatala

Started by Omowale, Apr 14, 2023, 09:26 PM

Previous topic - Next topic

Omowale

3e2938a0c177d54e1a73f098c07e8835.jpg

Òrìṣà Eepa ! 📿🤍⬜

Let us repeat the following Ìwúre 🙏🏾:


Ọ̀rìṣà ni màá sìn
Ẹni tó ṣe ojú
Ọ̀rìṣà ni màá sìn
Ẹni tó ṣe imú
Ọ̀rìṣà ni màá sìn
Ẹni tó ṣe ẹnu
Ọ̀rìṣà ni màá sìn
Ẹni tó ṣe etí
Ọ̀rìṣà ni màá sìn
Ẹni tó ṣe apá
Ọ̀rìṣà ni màá sìn
Ó dá mi bi ó ṣe fẹ́

⬜⬜⬜⬜⬜⬜⬜⬜⬜⬜⬜⬜⬜⬜

It is Orisha I will worship
The one who created eyes
It is Orisha I will worship
The one who created nose
It is Orisha I will worship
The one who created mouth
It is Orisha I will worship
The one who created ears
It is Orisha I will worship
The one who created arms
It is Orisha I will worship
He created me how he wanted
🐌🐚🕊�🙏🏾

In this Ìwúre we pay homage to Obatala (Òrìṣàńlá) for creating humanity - ìbà Òrìṣàńlá 🙏🏾

~Manifest destiny from within~

Ayobamikale

Àṣẹ 🤲🏿 Ẹ ṣeun fún ìwúre yìí
Láti ọwọ́ Ayọ̀bámikalẹ́